WPTranslationDay 2022 - Yorùbá Community

Hosted By
Theophilus A.

Details
E n le o 👋🏽
Inu mi dun lati sofun yin pe WordPress Translation Day Odún yi yio waye ni Ojó kejìdínlógbòn Osù Kesàán Odún yi.
Odoodun ni WordPress ma n see ajoyoyo yi. Gbogbo awon egbe kookan ti o n se itumo si WordPress lagbaye yio parapo loniruru ona lati sajoyo naa
Gege bi WordPress Yorùbá ti se je okan ninu awon egbé yi. A o ko ipa tiwa ninu ajoyo naa.
Ni Ojó naa, a o korapo Lori Google Meetup lati Jo setumo si WordPress ni èdè Yorùbá, ati lati yanayan awon ohun kookan ti o se Pataki lawujo isetumosi WordPress
Òrò mi kò lopin. Ìpàdé di Ojó náà 🥳
Fun alaye lekunrere si, e kan si ikanni ayelujara yii - https://wptranslationday.org/
✍🏽
Theophilus Adégbohùngbé
Oludari fun egbé WordPress Yorùbá

Ekiti WordPress Community
See more events
Online event
This event has passed
Sponsors
WPTranslationDay 2022 - Yorùbá Community